31Jétúrì, Náfísì, àti Kédámù. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Íṣímáẹ́lì
31
32Àwọn ọmọ Kétúrà, obìnrin Ábúráhámù: Àwọn ọmọ Jókísánì: Ṣébà àti Dédánì.
32Símíránì, Jókíṣánì Médánì, Mídíánì Iṣíbákì àti Ṣúà.
33Ọmọ Mídíánì: Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ìran Kétúrà.
33Éfà. Hénókì, Éférì, Ábídà àti Élídà.
34Ábúráhámù sì jẹ́ baba Ísáákì: Ísọ̀ àti Ísírẹ́lì.
34Àwọn ọmọ Ísáákì:
35Àwọn ọmọ Ísọ̀:
35Élífásì, Réuélì, Jéúsì, Jálámù, àti Kórà.
36Àwọn ọmọ Élífásì: làti Tímánà: Ámálékì.
36Témánì, Ómárì, Ṣéfì, Gátamù àti Kénásì;
37Àwọn ọmọ Réúélì:
37Náhátì, Ṣérà, Ṣámà àti Mísà.
38Àwọn ọmọ Ṣéírì:
38Lótanì, Ṣóbálì, Ṣíbéónì, Ánà, Díṣónì, Ésárì àti Dísánì.
39Àwọn ọmọ Lótanì:
39Hórì àti Hómámù. Tímínà sì jẹ́ arábìnrin Lótanì.
40Àwọn ọmọ Ṣóbálì: Àwọn ọmọ Ṣíbéónì: Áíyà àti Ánà.
40Álíánì, Mánánátì, Ébálì, Ṣéfì àti Ónámù.
41Àwọn ọmọ Ánà: Àwọn ọmọ Díṣónì: Hémídánì, Éṣébánì, Ítíránì, àti Kéránì.
41Díṣónì.
42Àwọn ọmọ Èsérì: Àwọn ọmọ Díṣánì: Húsì àti Áránì.
42Bílíhánì, Ṣáfánì àti Jákánì.
43Àwọn wọ̀nyí ni ọba tí ó jẹ ní Édómù, kí ó tó di wí pé àwọn ọba ará Ísírẹ́lì kán jẹ:
43Bélà ọmọ Béórì, ẹni tí orúkọ ìlú Rẹ̀ a máa jẹ́ Díníhábà.
44Nígbà tí Bélà kú, Jóbábù ọmọ Ṣérà láti Bósírà jẹ ọba dípò Rẹ̀.
44
45Nígbà tí Jóbábù sì kú, Húṣámù láti ilẹ̀ àwọn ará Témánì sì jẹ ọba ní ipò Rẹ̀.
45
46Nígbà tí Húṣámù sì kú, Hádádì ọmọ Bédádì, ẹni tí ó kọlu Mídíánì ní agbégbé Móábù, ó sì jẹ ọba ní ipò Rẹ̀. Orúkọ ìlú Rẹ̀ sì ni Áfítì.
46
47Nígbà tí Hádádì sì kú, Ṣámílà láti Másírékà, ó sì jọba ní ipò Rẹ̀
47
48Nígbà tí Ṣámílà sì kú, Ṣáúlì láti Réhóbótì lórí odò sì jẹ ọba ní ipò Rẹ̀
48
49Nígbà tí Ṣáúlì sì kú, Báli-hánánì, ọmọ Ákíbórì sì jẹ ọba ní ipò Rẹ̀.
49
50Nígbà tí Báli-hánánì sì kú, Hádádì sì di ọba nípò Rẹ̀. Orúkọ ìlú Rẹ̀ sì ni Páì; àti orúkọ ìyàwó sì ni Méhélábélì ọmọbìnrin Métírédì, ọmọbìnrin Mésíhábù.
51Hádádì sì kú pẹ̀lú. Tímínà, Álífà, Jététì
51Àwọn olórí Édómù ni:
52Óhólíbámà, Élà, Pínónì.
53Kénásì, Témánì, Mísárì,
54Mágádíẹ́lì àti Ìrámù. Àwọn wọ̀nyí ni Olórí Édómù.