Ìwé Sáàmù 123:1-4 BYB2014 - Bible AI

1Ìwọ ní mo gbé ojú mí sókè sí, ìwọ tí ń gbé inú ọ̀run

2Kíyèsí, bí ojú àwọn ìránṣẹ́ kùnrin ti máa ń wo ọwọ́ àwọn baba wọn, àti bí ojú ìránṣẹ́-bìnrin ti máa ń wo ọwọ́ ìyá Rẹ̀ bẹ́ẹ̀ ni ojú wa ń wo OLÚWA Ọlọ́run wa, títí yóò fi ṣàánú fún wa.

2

3OLÚWA, ṣàánú fún wa, ṣàánú fún wa; nítorí tí a kún fún ẹ̀gàn púpọ̀ púpọ̀.

4Ọkàn wa kún púpọ̀ fún ẹ̀gàn àwọn onírera, àti fún ẹ̀gàn àwọn agbéraga.

Copyright © 2014 by Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide
v>