Ìwé Sáàmù 125:1-5 BYB2014 - Bible AI

1Àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé OLÚWA yóò dàbí òkè Síónì, tí a kò lè sí ní ìdí, bí kò ṣe pé ó dúró láéláé

2Bí òkè ńlá ti yí Jérúsálẹ́mù ká, bẹ́ẹ̀ ní OLÚWA yí ènìyàn ká láti ìsinsìnyí lọ àti títí láéláé.

3Nítorí tí ọ̀pá àwọn ènìyàn búburú kì yóò bà lé ìpín àwọn olódodo; kí àwọn olódodo kí o máa ba fi ọwọ́ wọn lé ẹ̀ṣẹ̀.

3

4OLÚWA ṣe rere fún àwọn ẹni rere, àti fún àwọn tí àyà wọn dúró ṣinṣin.

5Bí ó ṣe ti irú àwọn tí wọn yà sí ipa ọ̀nà wíwọ́ wọn; OLÚWA yóò jẹ́ kí wọn lọ pẹ̀lú àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀.

5Ṣùgbọ́n àlàáfíà yóò wà lórí Ísírẹ́lì.

Copyright © 2014 by Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide
v>